CAC HYMN 660
1. Adupe Oluwa Ajodun de, e yo! 2. Opo l'elegbe wa 3. Baba wa li orun, 4. 'Wo Oluw' ajodun Amin
F'ajodun oni,
O da emi wa si,
Ogo f'oko Re;
Pelu orin ayo
L'a o fi josin
Fun'bukun aye wa
On 'reti orun.
Ke, Aleluya!
A m'ore ope wa,
Tewo gb'ore wa.
Ni ko tun si mo;
Opo ti sako lo
Kuro lodo Krist'
A dupe Oluwa
Pe O da wa si,
O si tun ka wa ye
F'ajodun oni.
Awa se 'pinu
Pe a o sin Jesu
L'ojo aye wa,
Ao sise fun 'dagba
Soke ijo wa
Tit' ao fi je 'pe Re
Fun 'simi orun.
A fope fun O,
Je k'ire ajodun
Kari gbogbo wa;
A be O, Olorun,
Fun wa l'agbara
Lati sin O d'opin
Ojo aye wa.