mostbet kzhttps://mostbet-play.kz/1vinpinap
https://4rabet-official.com/https://mostbets-casino.kz/1 winhttps://casino-lucky-jet.com/4a bet

  1. Ha! Egbe Mi Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN 723

1. Ha! egbe mi e w'asia
Bi ti nfe lele!
Ogun Jesu fere de na,
A fere segun.

“D'odi mu, Emi fere de”
Beni Jesu nwi,
Ran 'dahun pada s'orun, pe
“Awa o di mu.”

2. Wo opo ogun ti mbo wa;
Esu nko won bo;
Awon alagbara nsubu,
A fe damu tan!

3. Wo asia Jesu ti nfe,
Gbo ohun ipe;
A o segun gbogbo ota
Ni oruko Re

4. Ogun ngbona girigiri,
Iranwo wa mbo;
Balogun wa mbo wa tete,
Egbe, tujuka!

Amin.