https://ru-pinup.ru/mostbethttps://pinup-play.in/https://pin-up-cazino.kz/
1win slotlucky jet slotmosbetlucky jet casinohttps://4abet.in/

  1. Adupe Oluwa Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN 660

1. Adupe Oluwa
F'ajodun oni,
O da emi wa si,
Ogo f'oko Re;
Pelu orin ayo
L'a o fi josin
Fun'bukun aye wa
On 'reti orun.

Ajodun de, e yo!
Ke, Aleluya!
A m'ore ope wa,
Tewo gb'ore wa.

2. Opo l'elegbe wa
Ni ko tun si mo;
Opo ti sako lo
Kuro lodo Krist'
A dupe Oluwa
Pe O da wa si,
O si tun ka wa ye
F'ajodun oni.

3. Baba wa li orun,
Awa se 'pinu
Pe a o sin Jesu
L'ojo aye wa,
Ao sise fun 'dagba
Soke ijo wa
Tit' ao fi je 'pe Re
Fun 'simi orun.

4. 'Wo Oluw' ajodun
A fope fun O,
Je k'ire ajodun
Kari gbogbo wa;
A be O, Olorun,
Fun wa l'agbara
Lati sin O d'opin
Ojo aye wa.

Amin