pinuphttps://ru-pinup.ru/pin up1 win az
luckyjethttps://pin-up-bet.in/https://mostbets-casino.kz/pin-up kzluckyget

  1. Gbo Iro Li Opopo Aiye Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN 767

1. Gbo iro li opopo aye
Bi ti igbi omi okun,
Ti nfi agbara re ru s'oke
T'o si nkolu ebute.

Gbo iro ese omo ogun
Bi won ti nrin lo li ona na,
Are mu won fun 'se at'irin ajo
Ati ija kikoro;
Sugbon won gbagbo, won tejumo
Ona na t'awon mimo ti nrin,
Bi won ti nlo ni 'gbagbo
Won ndagba n'nu Olorun Alaye

2. Won ntesiwaju pelu 'gbagbo
Ti ekokeko ko le mi;
Won gbagbo pe oro Olorun
Le pese f'aini gbogbo.

3. Dapo mo won, aye wa sibe,
Duro de 'bukun Olorun;
Oun ni 'reti gbogbo agbaye
Lati sise ododo.

Amin.