1. Isun Kan wa to kun feje Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN 284

1. Isun kan wa to kun feje,
T'o ti'ha Jesu yo;
Elese mokun ninu re,
O bo ninu ebi.

A sa l'ogbe, n'tori 'rekoja,
A si pa lara, n'tori ese wa,
Ina alafia wa mbe l'ara Re
Ina Re lo nwo wa san;
A sa l'ogbe n'tori 'rekoja,
A sa l'ogbe n'tori 'rekoja,
Ina Re lo nwo wa san,
Ina Re nwo wa san.

2. Ole ni lor'agbelebu,
Yo lati ri 'sun na,
Bi mo kun f'ese bi tire,
Mo le we n'n' eje na.

3. Gba mo figbagbo r'isun na
Ti nsan fun eje Re
Irapada d'orin fun mi,
Ti un o ma ko titi.

4. Agbara to wa n'n' eje yi
Yo wa titi laelae,
Tit'won eni 'rapada,
Yo bo sinu ogo.

Amin.