CAC HYMN 288
Gbogb' ogo, iyin, ola 1. 'Wo l'Oba Israeli, 2. Egbe awon Maleka 3. Awon Heb'ru lo s'aju 4. Si O s'aju iya Re, 5. 'Wo gba orin iyin won, Amin.
Fun O Oludande,
S'Eni t'awon omode
Nko Hosanna didun!
Om'alade Dafid'
T'O wa l'oko Oluwa;
Oba Olubukun,
Nyin O l'oke giga;
Awa at'eda gbogbo
Ni dapo gbe “rin na.
Pelu imo 0pe;
Iyin, adua at'orin
L'a mu wa 'waju Re
Won korin iyin won!
'Wo t'a gbega nisiyi
L'a nkorin iyin si.
Gb'adura t'a mu wa,
'Wo ti nyo s'ohun rere,
Oba wa Olore,