пинапhttps://1-win-oyunu.com/pin up kzmostbet
mosbetlucky jet casino1win kz4x betluck jet

  1. Ife Pipe to Tayo Ero Eda Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN 509

1. Ife pipe, t'o tayo ero eda,
Niwaju Re l'a wole l'adura
Pe, ki ife ailopin le je t'awon
Ti Iwo so d'okan titi aye.

2. Iye pipe, ma je igbekele won
Fun ife on igbagbo ododo;
Fun ireti on emi ifarada,
Pelu 'fokantan lai beru iku.

3. Fun won l'ayo ti nbori ibanuje
Fun won l'alafia ti nm'aye dun,
Titi owuro ologo y'o fi mo;
Ojo ife on iye ailopin.

Amin