1 winmostbetpin up1vin
snai casino it1vinpin-up kz4a bet1win turkey

  1. Gbogbo Ogo Iyin Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN 288

Gbogb' ogo, iyin, ola
Fun O Oludande,
S'Eni t'awon omode
Nko Hosanna didun!

1. 'Wo l'Oba Israeli,
Om'alade Dafid'
T'O wa l'oko Oluwa;
Oba Olubukun,

2. Egbe awon Maleka
Nyin O l'oke giga;
Awa at'eda gbogbo
Ni dapo gbe “rin na.

3. Awon Heb'ru lo s'aju
Pelu imo 0pe;
Iyin, adua at'orin
L'a mu wa 'waju Re

4. Si O s'aju iya Re,
Won korin iyin won!
'Wo t'a gbega nisiyi
L'a nkorin iyin si.

5. 'Wo gba orin iyin won,
Gb'adura t'a mu wa,
'Wo ti nyo s'ohun rere,
Oba wa Olore,

Amin.