CAC HYMN 509
1. Ife pipe, t'o tayo ero eda, 2. Iye pipe, ma je igbekele won 3. Fun won l'ayo ti nbori ibanuje Amin
Niwaju Re l'a wole l'adura
Pe, ki ife ailopin le je t'awon
Ti Iwo so d'okan titi aye.
Fun ife on igbagbo ododo;
Fun ireti on emi ifarada,
Pelu 'fokantan lai beru iku.
Fun won l'alafia ti nm'aye dun,
Titi owuro ologo y'o fi mo;
Ojo ife on iye ailopin.