CAC HYMN 188
1. Elese, e yipada, 2. Elese e yi pada, 3. Elese, e yi pada, 4. Iyemeji ha nse yin Amin.
Ese ti e o fi ku?
Eleda yin ni mbere
Tofeki e ba On gbe;
Oran nla ni O mbi yin,
Ise owo Re ni yin;
A! eyin alailope
Ese t' e o ko 'fe Re?
Ese ti o o fi ku?
Olugbala ni mbere;
Eni t'O gb'emi yin la;
Iku Re y'o j'asan bi?
E o tun kan mo 'gi bi?
Eni 'rapada ese
Te o gan or'ofe Re?
Ese ti e o fi ku?
Emi mimo ni mbere
Ti nfojo gbogbo ro yin;
E ki o ha gb'ore Re?
E o ko iye sibe?
Ati nwa yin pe, ese
T'e mbi Olorun ninu?
Pe ife ni Olorun
E ki o ha gboro Re?
K'e gba ileri Re gbo?
W'Oluwa lodo yin,
Jesu sun, w'omije Re;
Eje Re pelu nke pe:
Ese ti e o fi ku?