mosbetпинапpinup azpin up casino
https://1-win-kazino.kz/pinup4rabet indiasnaibetmostbet aviator

  1. Emi Yio San Ore Oyeyemi Sweet-Melody

CAC HYMN V07

1. Emi y'o san ore o f'Olorun mi)2x
Eni da mi si o latesi wa )2x
Fun jije, fun mimu, t'o n b'asiri mi
Fun ipese lojojumo l'ona ara jaburata
Ko je k'aye yo mi, loju elegan, aye mi Dara
Emi y'o fore han f'Olorun mi.

2. E jek' asajoyo f'ope oni)
Eni ba m'ore Re waka s'ope )2x
F'ori wa to dara, ti O nbukun fun wa
O fi'gbala da wa lola, O npese ohun gbogbo
Ko jek' awa segbe, loju elegan, O gbe wa ro o
Eni 'nu re ba dun je ko yo o.

3. Emi y'o yin Jesu, Oba Ogo)
Olu seun ara, O m'ayo mi kun )2x
O da mi lola o, O tun pe mi l'omo
O f'ohun atata le mi lowo, ohun ijinle to daju
Ko jek' eru ba mi, loju elegan o ye mi si o
Emi y'o yin Jesu, Oba ogo.

4. E je k'a fope han f'Olorun wa)
Eni da wa si o d'ojo oni )2x
O fun wa logbon o, O tun pe wa sagbo
Omo Igbala mura giri, ko ma foya rara rara
Duro ninu 'gbagbo, lojo aye re, a dara fun o
E jek'a f ope han f'Olorun wa.

Amin.