CAC HYMN 655
1. Wa, eyin Olope wa, 2. Oko Olorun l'a je 3. N'tori Olorun wa mbo 4. Beni, maa bo, Oluwa Amin.
Gbe orin ikore ga,
Ire gbogbo ti wole
K'otutu oye to de;
Olorun Eleda wa,
L'o ti pese f'aini wa;
Wa k'a rele Olorun
Gbe orin ikore ga.
Lati s'eso iyin Re
Alikama at'epo,
Ndagba f'aro tab' ayo
Ehu yo, ipe tele
Siri oka si kehin;
Oluwa 'kore mu wa
Je eso rere fun O.
Y'o si kore Re sile;
On o gbon gbogbo panti
Kuro l'oko re da nu;
Y'o f'ase f'awon angel'
Lati gba epo s'ina;
Lati ko Alikama
Si aba Re titi lae.
Si ikore, ikeyin
Ko awon eeyan Re jo
Kuro l'ese at'aro;
So won di mimo laelae
Ki won le ma ba O gbe
Wa t' Iwo t'angeli Re
Gbe orin ikore ga.